Kaabọ si Ipele RSH Nigeria Hub ninu ede Yoruba

Awọn ohun elo Idaabobo ati ibudo atilẹyin (RSH) foju si atilẹyin awọn ajo ni eka iranlowo lati tepamo ilana idaabo fun ilokulo Ibalopo ni onakana ati idukoko moni fun ibalopo (SEAH).

Ibudo orileede Naijiria je ara RSH sugbon a se eto hub yii ni pataki lati pese inranlowo fun awon ajo agbegbe keekee ti n'sise ni eka iranlowo (idagbasoke ati pajawiri) ni orileede Naijiria A ni ęgbẹ ti orilẹ -ede ti o wa ni Ilu Abuja ti o nse iṣakoso ti Naijiria Hub a tun rii daju wipe ipele naa n mojuto oro aabo rẹ.

O le ri gbogbo awọn irinṣẹ ati awọn ohun elo ti o wa ninu ede Yoruba ni isalẹ.

A ti gbe bogbo awọn irinṣẹ ati awọn ohun elo ti o wa ninu ede Yoruba kalẹ ni isalẹ, yala RSH tabi eyi ti kii ṣe RSH

Ifojusi àlàye Aa Bi Di aláwòrán ni lati ran awon ẹgbẹ àwùjọ ni Nàìjíríà lọ́wọ́ pelu irántí awọn kókó ọ̀rọ̀ àfisùn nipa ìdáàbòbò ní kiákiá ati ni irọrùn. Eni ti o kọ́kọ́ se àgbékalẹ̀ re ni ajùmọsọrọ…
Multimedia
The ABCD infographic aims to provide civil society organisations in Nigeria with quick and easy to remember facts about safeguarding. It was originally designed by independent consultant Kabati Baba…
Multimedia
This video, produced by the RSH Nigeria hub, introduces key concepts and processes related to safeguarding. Broadly, safeguarding means preventing harm to people – and the environment – in the…
Multimedia
Ètò alailewu fun awon CSO ti wọn sise pẹlu eka ọmọniyan àti Ìdàgbàsókè  ilaniloye alaworan.  Ilaniloye alaworan yii lo tẹle iwe Ba tin Ṣètò àti se igbekale Àwọn Ètò Ailewu, èyí tó wà níbí. 
Multimedia
Safe Programming for CSOs in Humanitarian and Development Settings Infographics. This infographic accompanies the document How to Design and Deliver Safe Programmes, available here.
Multimedia
Awon iwadi ti orile-ede yii ni a ṣe lati pese awon eri ti o le dari bi a se le ṣe Ibudo orile-ede fun ohun-elo Idaabobo ati ibudo Atileyin (RSH). Orisirisi ona ni a lo lati se iwadi yi.  Awọn ona…
Documents
The country assessments are designed to provide an evidence base that can inform the design of the national hubs for the Safeguarding Resource and Support Hub (RSH). Different approaches were…
Documents
Ilaniloye alaworan yi se igbekale ati alaye orisun isele ati awọn òunfà fífi ibalopo re ẹni jẹ, ilo aito pelu idunkoko mo ní nípa ibalopo (SEAH) ninu ile ise ti o wa fun ìrànwo. O se ayewo ipa ti…
Documents
This infographic presents and defines the root causes and risk factors of Sexual Exploitation, Abuse and Sexual Harassment (SEAH) within the aid sector. It explores the role of power and privilege as…
Documents
Sise awari eto idanileko fun Ìdáàbòbò? Eka iwadi ati Ibudo Atileyin (RSH) ti se igbekale ti o se akopo oun ti idaabobo je, bíi fífi ibalopo re ẹni jẹ,ilo aito ati idunkoko mo ní nípa ibalopo (…
Documents
Looking for a simple safeguarding training tool? RSH has produced a presentation which provides an overview of safeguarding, including Sexual Exploitation, Abuse and Sexual Harassment (SEAH).  The…
Documents
This infographic explains informed consent, why it is an important part of safeguarding and how to gather informed consent. It also outlines what confidentiality is and how organisations can ensure…
Multimedia
Ilaniloye alaworan yii salaye ifowosi leyin alaye, idi ti o fi je abala pataki ni idaabobo ati bi ati a se n gba ifowosi leyin alaye.  O tun salaye ohun ti adehun asiri je ati bi awon ile ise se le e…
Multimedia